Sola Allyson has released a brand new track titled “Imole”. Check out the lyrics, watch the video live performance, and download the mp3 audio below to enjoy !!!
Sola Allyson is a spirit-filled and graced gospel music soloist gifted for establishing the reign of God’s kingdom here on earth through inspirational gospel songs. Sola Allyson’s profile would be incomplete without acknowledging the mighty hands and Grace of God upon his life, the same grace at work in this life-giving, spirit-lifting, and career-changing song, Imole.
Download Mp3/Audio Here
Imole Lyrics
Jesu! Imole!
Ategun ati Afara S’ibi Imole Jesu! Eni t’O wa Ife Baba S’eni to fe d’omoJesu! Imole!
Ategun ati Afara S’ibi Imole Jesu! Eni t’O wa Ife Baba S’eni to fe d’omoJesu! Imole!
Ategun ati Afara S’ibi Imole Jesu! Eni t’O wa Ife Baba S’eni to fe d’omoImole, lati ‘nu Imole
O wa lati da wa pada S’ona Imole Ookun to gb’ aye Ko je k’ ‘on mo Imole Won dite mo mo o, Ife Baba Olorun ninu eniyan Eniyan ninu Olorun Ilekun awon aguntan S’inu ile aanu Ipase eni ti mo gba igbala ati ilaja s’odo Baba B’ aye ti n fi fun ni ko Imole s’ookun aye mi Olu se ‘wosan emi miJesu! Imole!
Ategun ati Afara S’ibi Imole Jesu! Eni t’O wa Ife Baba S’eni to fe d’omoJesu! Imole!
Ategun ati afara S’ibi Imole Jesu! Eni t’O wa Ife Baba S’eni to fe d’omoEni wa Imole
Won n ri Imole Won o mo Imole Won n dite imole Irora yen po gan Eje at’ omi san gan Sibe O s’ agbawi fun wa Wipe Baba dariji won Won o mo n t’ ‘on se S’ a ti mo ‘n a n se Baba, dariji wa o, nitori Imole Ninu irora Re, o tun fi iyonu mu ole *** O ni “Iya wo omo re, Omo wo iya Re” O kigbe lohun rara: “Olorun mi, eese t’ O ko mi i le…” “Eese to ju mi le, eese t’ O yin mi nu?” Oungbe po gan, oti kikan laye fun Un Awon to wa Imole o, won n fi ‘ya je Imole O ba pari, O pari! Imole f’ emi E s’owo Baba O pari!Nitori Imole
Aso ikele ya o Nitori Imole A le pe Baba ni Baba Nitori Imole Isa oku d’ofo Eni ba fe le wa d’omoJesu! Oga Ogo!
Olori Ogun Orun! Omo Alade Alaafia! Alase Orun! Aye Baba! Baba laaye o! Baba laye! Aye mi, Tire ni Tan Imole nipase mi Ogo mi k’o f’ogo fun O Ola mi k’o bu ola fun O!Jesu! Iwo ni ‘Mole!
Iwo ni Afara! S’ibi ategun Imole Jesu! Iwo ni Eni naa t’O wa Mo juba Re, Eni to so mi d’omoFor more, Send a message to: hello@songsvine.com