Tope Alabi has released a brand new track titled “Eyin Oluwa”. Check out the lyrics, watch the video live performance, and download the mp3 audio below to enjoy !!!
Tope Alabi is a spirit-filled and graced gospel music soloist gifted for establishing the reign of God’s kingdom here on earth through inspirational gospel songs. Tope Alabi’s profile would be incomplete without acknowledging the mighty hands and Grace of God upon his life, the same grace at work in this life-giving, spirit-lifting, and career-changing song, Eyin Oluwa.
Download Mp3/Audio Here
Eyin Oluwa Lyrics
Eje ka fope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po Eru ipaa re po o e Be laanu re duro o lai-lai, eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga o-o-o-o-o (egbe ga) Eyin Oluwa o, halleluyah O hun logaju o-o-o-o, halleluyahYin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo Yin oun ti Kerubu, Serafu korin si o Oun re ru awon omi okun, eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo (Eyin Oluwa o), eyin Oluwa o, halleluyah O hun logaju ooo, halleluyahNitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori ododo re ti kosaki Nitori irele ati fe re siwa Nitori agbara re topo pupo (agbara re po pupo)Eyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah Eyin Oluwa o, halleluyah O hun logaju oooo, halleluyahIyanju ogo re ti ki pade
Iyan wo ina re to kun fun abo Onu gbogbo to da, o da won dara-dara Ni ohun te angeli juba ni gbagboEyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah Eyin Oluwa o, halleluyah O n logaju oooo, halleluyahYin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a Yin in bawon torun un o o o Oun loni ife e waju loEyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah Eyin Oluwa o, halleluyah O un logaju oooo, halleluyahEyin o Oluwa o, halleluyah
Egbe e ga ooooo, halleluyah Eyin Oluwa o, halleluyah O n logaju oooo, halleluyah
For more, Send a message to: hello@songsvine.com